Upcoming event:OJOO ASA ATI ISE YORUBA

OJOO ASA ATI ISE YORUBA

Ojo Asa ati Ise Yoruba yio waye, pelu ogo Olohun, ni ojo Eti, Ojo Ketala, Osu Okudu, Odun 2015 (Ti O Se Deede Ojo Kerindinlogbon, Osuu Sha’ban, 1436)

Gbogbo awon obi ni a pe

 

Medmina College is set to provide the best secondary education possible for the Muslim child without compromising the child’s spiritual needs.